A nse awá rí awon ona ti odara ju ti ateyinwa fun sise agbekale awon ohun èlò êrô
olóye kömpútà nipa sisee ati riran awon elomiran lowo lati see.
Nipase ise yi a ti wa mo riri:
Eniyan ati ajosepo dipo igbese ati irinse
Ohun èlò ti on sise dipo iwe akosile ti o gbooro
Ajumosepo oníbàárà dipo iduna dura adehun ise
Idahun si iyipada dipo ti tele èrò
Eleyi ja si wipe, bi awon nkan ti o wa ni owo otun tile níyelórí
a mo riri awon ohun ti owa ni owo osi ju won lo.
|
Kent Beck Mike Beedle Arie van Bennekum Alistair Cockburn Ward Cunningham Martin Fowler |
James Grenning Jim Highsmith Andrew Hunt Ron Jeffries Jon Kern Brian Marick |
Robert C. Martin Steve Mellor Ken Schwaber Jeff Sutherland Dave Thomas |