Ilana Eto fun Sise Ohun Elo Ero Oloye Komputa Laijafira
A nse awari awon ona ti odara ju ti ateyinwa fun sise agbekale awon ohun elo ero
oloye komputa nipa sisee ati riran awon elomiran lowo lati see.
Nipase ise yi a ti wa mo riri:

Eniyan ati ajosepo dipo igbese ati irinse
Ohun elo ti on sise dipo iwe akosile ti o gbooro
Ajumosepo onibaara dipo iduna dura adehun ise
Idahun si iyipada dipo ti tele èrò

Eleyi ja si wipe, bi awon nkan ti o wa ni owo otun tile níyelórí
a mo riri awon ohun ti owa ni owo osi ju won lo.
Kent Beck
Mike Beedle
Arie van Bennekum
Alistair Cockburn
Ward Cunningham
Martin Fowler
James Grenning
Jim Highsmith
Andrew Hunt
Ron Jeffries
Jon Kern
Brian Marick
Robert C. Martin
Steve Mellor
Ken Schwaber
Jeff Sutherland
Dave Thomas© 2001, the above authors
this declaration may be freely copied in any form,
but only in its entirety through this notice.


Ofin ipile mejila Fun Sise Ohun Elo Ero Oloye Komputa Laijafira

Awon ti won ti sami lati darapo mo awon ojogbon

Nipa awon Olupileye
Nipa Ilana Eto Yi


Afrikaans
Albanian
Amharic
عربي
Azərbaycanca
Беларуская
Bosanski
Български
Català
Česky
Deutsch
Dansk
Ελληνικά
English
Español
Eesti
Euskara
Suomi
Français
Gaeilge
Gàidhlig
Galician
Galego
ქართული
עברית
हिंदी
Croatian/Hrvatski
Hungarian/Magyar
Bahasa Indonesia
Íslenska
Italiano
日本語
ខ្មែរ
한국어
Latviešu
Lietuvių
Македонски/Macedonian
Bahasa Melayu
မြန်မာစာ
नेपाली
Nederlands
Norsk
ଓଡ଼ିଆ
ਪੰਜਾਬੀ
Polski
فارسی
Português Brasileiro
Português Portugal
Română
Русский
සිංහල
Slovenščina
Slovensky
संस्कृत
Srpski
Svenska
Swahili
தமிழ்
తెలుగు
ภาษาไทย
Filipino
Türkçe
Xitsonga
Українська
اردو
Yoruba
繁體中文
简体中文


site design and artwork © 2001, Ward Cunningham
Itumo si Yoruba lati owo Tope Songonuga, pelu atileyin awon ojogbon Yoruba. © 2012